Olùkọ́ Ilé Ẹ̀kọ́ Gíga Fasiti Kan Ti Ké Sí Ìjọba Láti Ṣe Àmúlò Àṣà ìṣèjọba Àwa-ara-wa
Ọ̀mọ̀we Bayonle Busari ti ilé ẹ̀kọ́ gíga Fasiti Lead City, ni ìlú Ìbàdàn ti ké sí gbogbo ọmọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà láti dìde pẹ̀lú ohùn kan láti sọ fún àwọn adarí wọn kí wọn ṣe àmúlò àṣà ìṣèjọba àwa-ara-wa gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe n ṣe ni Orilẹ èdè…