Ìsọ̀kan Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ẹkun Gúsù Ìwọ̀ Oòrùn Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà: Makinde Àti Adeleke Fẹnu Kò
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ S'eyi Makinde àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Ademola Adeleke ti ṣèlérí láti fọwọ́sowọ́pọ̀ fún ìṣọ̀kan ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ni Ẹkùn Gúsù Ìwọ̀ Oòrùn..
Nígbà tó n sọrọ lórí ìdí pàtàkì tó fi ṣe ibẹwo sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,…