Take a fresh look at your lifestyle.

Àpejọ AFLPM: Àwọn obìnrin àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè adúláwọ̀ gúnlẹ̀ sí Nàìjíríà

Àwọn ìyáàfin àkọ́kọ́ ilẹ̀ adúláwọ̀ ń gúnlẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún Àpèjọ Gbogbogbòò ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn an irú ẹ̀ ti Ìgbìmọ̀ Àlàáfíà àwọn ìyáàfin àkọ́kọ́ (AFLPM,) tí  yóò wáyé ní Ọjọ́ ajé, ọjọ́…

Àjọ NEMA Ti Mú Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí Ìrìn Àjò Wọn Sí Ìlu ́Libya Ti Forí Sọ́npọ́n…

Aj̀ọ tó ń rí sí ètò pàjáwìrì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NEMA), ní ọjọ́ ọjọ́rú ti gba àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà marundinlọgọrun (95) tí ìrìn àjò wọn sí ìlú Libya ti forí sópón padà wá sí ìlú…
button