Wọn tí pá Seif al-Islam Gadhafi, ọmọ Moammar Gadhafi Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Libya Tẹ́lẹ̀, ní ìlú Zintan, gẹ́gẹ́ bí àwọn aláṣẹ Libya ti sọ.
Wọn kò tíì kéde ipò ikú rẹ̀ ṣùgbọ́n àwọn oníròyìn ń ròyìn pé àwọn agbebọnrin kan pa á nílé rẹ̀.
A bí Seif al-Islam ní oṣù kẹfà ọdún 1972, ó gba PhD ní ‘London School of Economics’, wọ́n sì rí i gẹ́gẹ́ bí ojú àwọn atúntò ìlù ní sáà ìjọba bàbá rẹ̀, Gadhafi.
Moammar Gadhafi ni wọ́n pá náà ní ìdìtẹ̀ àwọn ènìyàn pẹ̀lú àtìlẹ́yìn NATO ní ọdún 2011 lẹ́yìn tó tí ló ogójì ọdún (40 years) gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà.
Comments are closed.