Take a fresh look at your lifestyle.

Àhesọ Lásán Ní Ìròyìn Ìdáwó Padà Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ – NELFUND

100

Àjọ Àkànṣe Ètò Ìyáwó Ẹ̀kọ́ Nàìjíríà (NELFUND) tí kọ àwọn ìròyìn tó ń pàṣẹ fún àwọn olùgbádùn owó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìjọba àpapọ̀ láti bẹ̀rẹ̀ sí san padà.

‎Olùdarí Ìbánisọ̀rọ̀ ti owó náà, Arábìnrin Oseyemi Oluwatuyi nínú ìkéde kan sọ pé àjọ náà ti kíyèsí bí àwọn ìròyìn ṣe ń lọ káàkiri nínú àwọn ìròyìn àti lórí àwọn ìkànnì àwùjọ ayélujára tó ń sọ pé wọn tí paṣẹ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti bẹ̀rẹ̀ sí san àwọn owó awin wọn, ó sì ń tẹnumọ́ pé kò sí irú àṣẹ bẹ́ẹ̀ láti ọdọ àjọ náà.

Comments are closed.

button