Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ọmọ-ogun Nàìjíríà Pa Àwọn Àpániláyà Méjìlélọ́gọ́ta Ní Ìwọ̀-Oòrùn Àríwá

103

Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Àpapọ̀ àwọn Ọmọ-ogun ní Ìwọ̀-Oòrùn Àríwá tí á mọ́ sí ‘Operation FANSAN YAMMA’, ti ní àṣeyọrí tuntun nípa pípa àwọn Àpániláyà ní Ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n sì gba àwọn méjìlélọ́gọ́ta (62) tí wọ́n jigbé ní Ìpínlẹ̀ Zamfara la.

‎Àwọn ọmọ-ogun wọ̀nyí ní wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun ààbò àti àwọn ọmọ-ogun ìbílẹ̀, wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ láti kojú àwọn onijakidijagan àti àwọn ajínigbé ní Ìwọ̀-Oòrùn Àríwá.

Comments are closed.

button