Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Tí Wà Ní Ipò Kẹrìndínlọ́gbọ̀n Nínú Àkàbà ìdíje FIFA Tuntun

93

Ikọ̀ Agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà (Nigeria Super Eagles) ti wà ní ipò kẹrìndínlọ́gbọ̀n nínú àkàbà ìdíje FIFA tuntun, wọ́n sì ń gòkè sí ipò kẹta ní Áfíríkà.

‎ Lágbàáyé, Spain ló dúró ní ipò àkọ́kọ́, lẹ́yìn náà ni Argentina àti Faransé, nígbà tí England, Brazil, Portugal, Netherlands, Belgium, Germany àti Croatia parí àwọn mẹ́wàá tó wà lórí akásọ náà.

Comments are closed.

button