Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìbílẹ̀ Abia Ti Gbáradì Láti Se Ìdásílẹ̀ Ibùdó Ìsàyẹ̀wò Ohun Èlò Ìkọ́lé

224

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Abia ti buwọ́lu ìsàgbékalẹ̀ ibùdó ìsàyẹ̀wò ohun èlò ìkọ́lé ní ìlú Umuahia

 

Ìgbésẹ̀ náà wáyé láti dènà lílo àwọn ohun èlò ayédèrú, lójúnà àti gbógunti ìsẹ̀lẹ̀ ilé dídàwó ní àwùjọ

 

Alákòóso ètò ìkọ́lé àti ìdàgbàsókè àwùjọ, Ọ̀gbẹ́ni Kingsley Agomoh ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ìlú Umuahia, níbi tí ó ti fi ìgbáradì ìjọba hàn láti se àmójútó àwọn ohun èlò ìkọ́lé láwùjọ.

 

 

Comments are closed.

button