Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kí Etsu Nupe kú órire Ọjọ́ Ìbí Ọ̀kànlẹ́láàdọ́rin.

0 323

Ààrẹ Bola Tinubu ti kí Ọba Etsu Nupe,Alhaji Yahaya Abubakar, kú órire ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Ọ̀kànlẹ́láàdọ́rin.

Ààrẹ ní láti ogún ọdún tí ọba náà dé orí ipò kò sí àkọlé aburú nipa rẹ rárá.

Ààrẹ ṣe àpèjúwe Ọba gbajumọ náà, tó tún jẹ́ alága fún àwọn lọ́balọ́ba ni ìpínlẹ̀ Niger gẹ́gẹ́ bí ẹni ìyìn àti ẹni àpónlé láwùjọ.

Ààrẹ wà gbàdúrà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún nínú àlàáfíà, o sí rọ láti jẹ olóòótọ èyí yóò jẹ́ apẹrẹ réré fún àwọn ènìyàn

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button