Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Tinubu ṣe ìpàdé pẹ̀lú àwọn aṣojú láti Orílẹ̀-èdè UAE, ṣáájú ọjọ́ ìpàdé àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè gbogbo.
Ọ̀gá àgbà pátápátá fún àwọn òṣìṣẹ́ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fẹmi Gbajabiamila, Nuhu Ribadu àti àwọn Mínísítà fún ọ̀rọ̀ òkèrè náà wa níbí ìpàdé náà
Ààrẹ ṣe ìbẹ̀wọ̀ sí Abu Dhabi lẹ́yìn ìpàdé G20 ni Orílẹ̀-èdè India, láti sọ̀rọ̀ lórí idojukọ èyí tó n ṣe àkóbá fún àwọn Orílẹ̀-èdè méjèjì àti ọ̀nà Ábáyọ àti láti ti mu ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀rọ̀ ajé ni Orílẹ̀-èdè náà.
Leave a Reply