Àjọ Nigeria Premier Football League (NPFL) ti kéde ìsún síwájú eré bọ́ọ̀lù ti ìbẹ̀rẹ̀ Sáà ọdún 2023/2024 látàrí ki àwọn ọmọ ẹgbẹ́ leè rí àyè láti gbaradì fún Annual General Meeting (AGM) ti àjọ Nigeria Football Federation (NFF) tó ń wáyé ní ìlú Uyo, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.
Ọ̀ga ti wọ́n ń pè ní Chief Operating Officer (CEO), Davidson Owumi, sọ pé wọ́n ti fi tó àwọn gbogbo ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù létí kí wọ́n leè tètè bẹ́gi dínà ìrìn-àjò tí wọ́n ti ní lọ́kàn tẹ́lẹ̀
Ó sọ pé ọjọ́ tuntun ti wọn yóò sun sí yóò di mímọ ní àìpẹ
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply