Ilé ẹjọ́ tí ó ń gbọ́ awuye-wuye lórí ìdìbò gbogbogbòò tí ó wà ní ìlú Abuja ti sún ìdájọ́ síwájú látàrí ẹjọ́ tí olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú Lp, ọgbẹni Pater Obi pè tako ìjáwé olúborí ààrẹ Tinubu .
Obi rọ ilé ẹjọ̀ láti fagilé kíkéde ààrẹ Tinubu gẹ́gẹ́ bí ẹni ti o jáwé olúborí nínú ìdìbò gbogbogbòò ti o waye ni ojọ kẹẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n osù keji.
Alága àwọn olùgbẹ́jọ́ náà, adájọ́ Simon Tsammani, nígbà tí ó n sún ìdájọ́ náà síwájú sọ pé, òun yóò se ìfiléde ọjọ́ tí ìdájọ́ náà yóò wáyé fún àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn.
.
Leave a Reply