Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Tí Ó Gún Régé Gbọdọ̀ Wáyé Lórí Ìsàmúlò Owó Ìrànwọ́ Tí Ìjọba Àpapọ̀ Se Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọ̀gbìn- Àjọ elétò Ọ̀gbìn Ké Gbàjarè

0 221

Àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn ní abala ètò ọ̀gbìn ti pè fún ìkẹ́ṣejárí lórí ìsàmúlọ̀ igba bílíọ̀nù owó ìrànwọ́ tí ìjọba àpapọ̀ se láti mú ìgbòòrò bá ìpèsè oúnjẹ àti àwọn ohun èlò fún ètò ọ̀gbìn

 

Àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ pe ìpè náà níbi ìfọ̀rọ̀-wáni-lẹ́nu-wò tí ó wáyé ní ọjọ́ Ajé ní ìlú Èkó níbi ìsàgbéyẹ̀wò ìfiléde tí Ààrẹ Tinubu se, èyí tí àkọmọ̀nà rẹ̀ jẹ́ “lẹ́yìn òkùnkùn, ìmọ́lẹ̀ lókàn”.

 

Àjọ náà ń gbìyànjú láti mú èròńgbà ìjọba àpapọ̀ pẹ̀lú ìsàgbékalẹ̀ owó tùùlù náà ṣẹ, láti lé ìṣẹ́ wọ̀gbẹ́, tí oúnjẹ yóò sì sùwábọ̀ lọ́pọ̀ yanturu.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button