Take a fresh look at your lifestyle.

Mo Sí Dúró Lórí Ìjọba Tó Nṣe Dáradára: Gómìnà Makinde.

0 198

Gómìnà Makinde tí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ fí ọwọ́ sọ yà wípé ìjọba òhun sí ń tèsíwájú nínú ìṣọkan pẹ̀lú àwọn ìjọba tó kún fún ìlọsíwájú ìjọba,tí àwọn ará ìlú yóò fi yangàn.

 

Ọ̀rọ̀ ìdánilójú yìí ló wáyé láti ẹnu Gómìnà Makinde nígbàtí o ń búra fún adájọ́ tuntun ní ìpínlẹ̀ náà,Iyabo Yetima, èyí tó wáyé ní ilé àwọn adájọ́ tí o wà ní ilé ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni Agodi, ibadan.

 

Gómìnà rọ adájọ́ tuntun láti má ṣe òjúṣàájú nínú ìdájọ tó bá wà sí iwájú rẹ.

 

Adájọ́ tuntun náà ṣe ìlérí láti ṣiṣẹ rẹ pẹ̀lú òtítọ àti ìbẹrù ọlọrun nínú.

Ó tèsíwájú wípé òhun yóò gbé ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lẹ́yìn fún ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button