Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Anambra Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Elétò Ìlera

0 448

Ọ́ọ́fìsì alákòsóo ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Anambra ti parí idánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ méjì tí ó se fún àwọn elétò ìlera, fún ìdáàbòbò, ìtọ́jú àti ìdènà àwọn àrùn nì ìpínlẹ̀ náà.

 

Eléyìí wáyé ní gbàngàn ibùdó ètò ìlera ní Awka, ìpínlẹ̀ Anambra.

 

Nígbà tí ó n sọ̀rọ̀ níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà, arábìnrin Adaobi Ezeani sọ pé, ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà dá lórí àrùn ìtọ̀ súgà (Diabetes), àti ẹ̀jẹ̀ rúru (hypertension). Èyí yóò jẹ́ kí wọ́n mọ ọ̀nà láti tọ́jú àwọn àrùn náà.

 

Dókítà Chukwudi àti Dokita Nwagbara tún sàlàyé lórí àwọn àìsàn náà àti bí a se ń ṣe ìtọ́jú wọn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button