Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Aṣáájú Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Dábàá Àtúnṣe SibÌwà Ọ̀daràn Ààlà

70

Ọ̀kan nínú àwọn Olórí Àgbà ti ẹgbẹ́ òṣèlú ‘All Progressives Congress APC’, Sẹ́nétọ̀ Lola Ashiru ti ké sí àwọn ìjọba ní gbogbo ìpele láti mú ààbò ààlà lágbára síi nípa mímú ọrọ-ajé àwọn agbègbè ààlà pọ̀ sí i.

‎ Ashiru tó ń ṣojú fún Gúúsù Kwara nílé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀-èdè ṣe ìpè náà nígbà tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ akọroyin tí Nàìjíríà (Nigeria Union of Journalists NUJ), tí Ìpínlẹ̀ Kwara, ṣe ìbẹ̀wò sí i.

‎Ó tẹnu mọ́ ọn pé Ìdàgbàsókè ọrọ-ajé àwọn agbègbè ààlà yóò dín ìgbòkègbodò ìwà ọ̀daràn kù ní kíákíá.

Comments are closed.

button