Take a fresh look at your lifestyle.

ADP Ṣe Ìgbìmọ̀ràn Ìlànà Pẹ̀lú Atiku Abubakar

63

Àwọn olórí ẹgbẹ́ òṣèlú ti ‘Action Democratic Party, ADP’, ṣe ìpàdé ìgbìmọ̀ràn gíga pẹ̀lú Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí, Atiku Abubakar, gẹ́gẹ́ bí apá kan nínú àwọn ìbáṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn alẹnu-lọrọ lórí ìjọba tiwantiwa.

‎Gẹ́gẹ́ bí ìkéde tí Alága ẹgbẹ́ ADP, Ọ̀gbẹ́ni Yabagi Sani, fi síta, sọ pé “Ìpàdé náà dojúkọ ìdídáàbòbò ìjọba tiwantiwa, ríró àwọn ẹgbẹ́ alátakò lágbára síi, àti dídáàbòbò àwọn àṣàyàn ìdìbò tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé kí ìdìbò gbogbogbòò ọdún 2027 tó dé”.

Comments are closed.

button