Take a fresh look at your lifestyle.

Wọn Ti Pá ‘Seif Gadhafi’ Ọmọ Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Libya Tẹ́lẹ̀ Rí ‎

41

Wọn tí pá Seif al-Islam Gadhafi, ọmọ Moammar Gadhafi Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Libya Tẹ́lẹ̀, ní ìlú Zintan, gẹ́gẹ́ bí àwọn aláṣẹ Libya ti sọ.

‎Wọn kò tíì kéde ipò ikú rẹ̀ ṣùgbọ́n àwọn oníròyìn ń ròyìn pé àwọn agbebọnrin kan pa á nílé rẹ̀.

‎A bí Seif al-Islam ní oṣù kẹfà ọdún 1972, ó gba PhD ní ‘London School of Economics’, wọ́n sì rí i gẹ́gẹ́ bí ojú àwọn atúntò ìlù ní sáà ìjọba bàbá rẹ̀, Gadhafi.

‎Moammar Gadhafi ni wọ́n pá náà ní ìdìtẹ̀ àwọn ènìyàn pẹ̀lú àtìlẹ́yìn NATO ní ọdún 2011 lẹ́yìn tó tí ló ogójì ọdún (40 years) gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Orílẹ̀-èdè náà.

Comments are closed.

button