Olórí Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Ojú-omi Nàìjíríà, ‘Vice Admiral’ Idi Abbas (Admiralty Medal), ti fọwọ́ sí yíyàn Abiodun Folorunsho gẹ́gẹ́ bí Olùdarí Ìròyìn àwọn ọmọ ogún Ojú-Omi àti Agbẹnusọ Ilé-iṣẹ́ náà.
Folorunsho gba ipò náà lọ́wọ́ Commodore Aiwuyor Adams-Aliu tó ti ń ṣiṣẹ́ láti bí ọdún méjì lè díẹ̀ tí gbá ìgbéga lẹ́nu ìṣe gẹ́gẹ́ bí Aláṣẹ Ọkọ̀ Ojú Omi Nàìjíríà BEECROFT.
Comments are closed.