Ẹgbẹ́ òṣèlú ‘All Progressives Congress APC’ ní Ìpínlẹ̀ Anambra tí ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìforúkọsílẹ̀ pẹ̀lú imọ-ẹ̀rọ ní gbogbo ìpínlẹ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó wà tẹ́lẹ̀ àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun, gẹ́gẹ́ bí apá kan lára àwọn ìsapá wọn láti gbá gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ wọn jákèjádò Nàìjíríà kò tó di ọdún 2027.
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìforúkọsílẹ̀ náà ń wáyé ní gbogbo agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mọkanlelogun (21) ní ìpínlẹ̀ náà.
Nígbà tí àwọn alẹnu-lọrọ ń sọ̀rọ̀ níbi ìpàdé APC tó wà ní Awka, àwọn olórí ẹgbẹ́ náà sọ pé ètò náà fẹ́ forúkọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun tó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà irinwó (400,000).
Comments are closed.