Take a fresh look at your lifestyle.

5

Ìperegedé Fún Davis Cup: Djokovic Kólé Kópa Pẹlú Ìkọ Serbia Nítorí Àìlera

‎ Àgba bọọlu ẹlẹyin lórí tábìlì, Novak Djokovic, ní kò nílé kópa fún ìkọ Serbia níbí ìdíje iperegedeé Davis Cup nítorí àìlera, àwọn alákòóso tẹ́nìs tí orílẹ̀-èdè náà (TSS) sọ.

‎ Djokovic, tó tí pinnu látí ṣé aṣojú Serbia ní ọjọ́ kọkànlélọgbọ̀n Oṣù Kíní sí ọjọ́ Kejì oṣù keji ọdún yìí (Jan. 31st – 2nd Feb.) pẹ̀lú Denmark ní Copenhagen, tí fẹyìntì nítorí ìpalára tó ní níbí ìdíje ‘Australian Open’ rẹ pẹ̀lú Alexander Zverev ní ọsẹ tó kọjá.

‎Djokovic ní àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè náà tí bú ẹnu àtẹ lù, tí wọn sì kọ’rin eebu lè ní Melbourne Park. O sí dá wọ́n lóun pẹ̀lú àwòrán MRI r látí fí ṣé ẹrí

‎ Djokovic, 37, wà lára ìkọ Serbia tó gbá ife ẹyẹ́ Davis Cup ní odún 2010 bí wọ́n ṣé bóri ìkọ France ní Belgrade.

Comments are closed.

button