Take a fresh look at your lifestyle.

9

Ètò Ààbò Ni Ipinleo Oyo: Ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Oyo Pọn dandan Nomba Ọkọ.

 

 

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Oyo ti ṣe ofin wí pé o Pon dandan fún gbogbo ọkọ́ láti ni nọmba ìdánimọ̀.

 

Wọn ní èyí yóò ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ètò ààbò ni ìpínlẹ̀ náà.

 

Òfin yìí ni Ọ́nárébù R.A Mabaje láti ( Idọ), Ọ́nárébù Adebo Ogundoyin láti (ìbàràpá), Ọ́nárébù S.A Onaolapo láti Ogbomosho àti Ọ́nárébù Bamidele Adéọlá láti Iseyin Itesiwaju ka sí inú ìpàdé lásìkò ìpàdé.

 

Gbogbo ilé ni òfin jẹ ohun tí yóò dènà ìwà ìbàjẹ́ láàrin ìlú.

 

Wọn ní yóò dènà ìwà ajumọgbe, apànìyàn, olè àti bẹbẹ lọ to n ṣẹlẹ laarin ìlú.

 

Wọn ní bí nkan ba wáyé ko sí ibi tí wọn wá sí nígbà tí ko sí nọmba ìdánimọ̀ lára ọkọ̀.

Comments are closed.

button