Mínísítà fún ẹ̀tò isẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ David Umahi ti sí iṣẹ́ òpópó-ònà ti yóò dènà omí yalé ni ìpínlẹ̀ Keebi.
Abdullahi Tanko Yakasai to jẹ ìgbà Kejì pàtàkì fún Ààrẹ ni nípa ọ̀rọ̀ agbègbè ló sojú mínísítà ni sí sì òpópó-ònà naa
Ó ní Ààrẹ Tinubu ni o buwọ́lu isẹ́ náà láti Ọdun 2024 láti rí wí pè ìjàmbá omí dẹkun ni ìpínlẹ̀ náà.
Yakasai ni èyí yóó mu idojukọ dì kun fún àwọn ará àgbègbè náà ki wọn gbè ni àlàáfíà Lai sí ifoya
Ó wá fi idunnu re hàn bi isẹ ṣe n ló ati bi wọn ṣe mu ìdàgbàsókè bá ìjoba ìpínlẹ̀ Keebi