Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Sọ Ilé-ìwé Kọ́lẹ́ẹ̀jì Ìmọ̀-ẹ̀rọ Alákọ́bẹ́rẹ̀ Dí Ọ̀fẹ́ Jákèjádò Orílẹ̀-èdè ‎

92

Ìjọba Nàìjíríà, tún ṣàfihàn ìdúróṣinṣin rẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ ọ̀fẹ́ àti ìdàgbàsókè Ilé-ìwé Kọ́lẹ́ẹ̀jì ìmọ̀-ẹ̀rọ alákọ́bẹ́rẹ̀, bí wọn ṣe kéde ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ jákèjádò Orílẹ̀-èdè láti mú kí ìdàgbàsókè ìmọ̀-ẹ̀rọ pọ̀ sí i.

‎ Ilé-iṣẹ́ Ẹ̀kọ́ tí Orílẹ̀-èdè ni ó kéde èyí lẹ́yìn tí Mínísítà fún Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Tunji Alausa, fọwọ́ sí ètò náà.

Comments are closed.

button