Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Kí Alága NRS Zacch Adedeji Ẹní Ọmọ Ọdún mẹ́tàdínlàádọ́ta ‎

64

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí Alága fún Iṣẹ́ Owó-orí Nàìjíríà (NRS), Dókítà Zacch Adedeji, ní ayẹyẹ Ọjọ́ìbí rẹ̀, O gbóríyìn ìtọ́sọ́nà rẹ̀ lórí ìyípadà ilé-iṣẹ́ owó-orí orílẹ̀-èdè náà.

‎ Nínú ìròyìn kán tí Agbẹnusọ Ààrẹ fi síta, Ààrẹ yìn Dókítà Adedeji fún mímú àwọn èrò tuntun àti àwọn ìṣe tó dára jùlọ, pàápàá jùlọ nípasẹ̀ àtúnṣe àwọn ètò àti mímú àwọn òṣìṣẹ́ pọ̀ sí i láti mú kí iṣẹ́ wọn sunwọ̀n sí i àti ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè.

‎Ààrẹ Tinubu ṣàpèjúwe Alága NRS gẹ́gẹ́ bí aṣáájú oníran àti onímọ̀lára tí ìyàsímímọ́ rẹ̀ àti iriran rẹ̀ àti ṣe àtúnṣe láti mú kí ìrísí owó-orí Nàìjíríà lágbára sí i.

Comments are closed.

button