Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣètò láti gbàlejò àwọn ilé-iṣẹ́ ọkọ̀ ayọkẹlẹ oníná bí Orílẹ̀-èdè China tí n kéde ìpinnu wọ́n.
Aṣojú Ilú China sí Nàìjíríà, Yu Dunhai, sọ èyí l’àkókò àbẹwò kán sí Mínísítà fún Àwọn òun alumọni tó lágbára tí Nàìjíríà, Dele Alake.
Dunhai tẹnumọ pàtàkì tí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin China àti Nàìjíríà, ṣé àkíyèsí pé ìdásílẹ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ ọkọ̀ ayọkẹlẹ oníná le ṣé ìrànlọ́wọ́ látí ṣé atọ́ka nlá si ẹka àwọn òun alumọni tí Nàìjíríà
Comments are closed.