Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Nàìjíríà Tí Fọwọ́sí Gbígba Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Igbó ‎

Lekan Orenuga

159

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí ìgbanísíṣẹ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́ igbó gẹ́gẹ́bí isọdọtun àwọn ìlànà orílẹ̀-èdè láti ní Ààbò àti gbá àwọn igbó Nàìjíríà pàdà lọwọ́ àwọn ọ̀daràn àti àwọn arufín ilú.

‎ Ìpinnu náà ní èròngbà látí tẹra mọ iṣẹ́ ààbò àyíká, gbógun tí gígé ìgi nínú igbó lọnà áìtọ́, àti látí kojú àwọn tó f’igbo bójú ṣe ibí, àwọn agbebọn, àwọn ọlọtẹ ilú àti àwọn mìíràn.

‎ Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Igbó náà yóó gbá ìkẹ́kọ̀ọ́ pàtàkì pẹ̀lú àwọn oún èlò, kí a tó ràn wọ́n lọ́ káàkiri àwọn ìgbèríko pẹ̀lú ìlànà ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò yòókù.

‎ Àlàyé yìí ní o jáde nínú àlàyé kán tí Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Ààrẹ lórí ìkéde àti Ibaraẹnisọrọ Gbogbo ènìyàn, Sunday Dare, nípasẹ ẹrọ ayélujára ‘X’ rẹ̀, @SundayDareSD.

Comments are closed.

button