Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Kaduna: Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Náà Parapò Láti Ṣe Àjoyọ́ Ọjọ́ Àlàáfíà.

51

Àwọn ará agbègbè ìpínlẹ̀ Kaduna ti pejo láti ṣe àfihàn ifẹ, irepo àti ìsọkan láàrin ara wọn ní ojọ́ kerindinlogun oṣù kàrún ọdún, 2025.

Ààrẹ ẹgbẹ́ àlàáfíà ti onigbagbọ wọn pẹ ni PRRFON  alàgbà Buru kí àwọn ènìyàn tó jẹ Musulumi káàbò sí ilé rẹ, nibe ni won ti pinu láti ni ajoyọ àlàáfíà láàrin ara wọn.

Ó ní ayajọ ọjọ́ àlàáfíà náà yóò mú àlàáfíà àti ìdàgbàsókè ba àwọn ará ìlú àti  wí pé yóò ọjọ́ iwájú àwọn ọmọ tó n no lẹyìn wa dára fún irẹpọ.

Alàgbà Buru ni o ṣe pàtàkì láti ni agbọye ati ìfẹ láàrin ara wa kí ìsọkan ati irẹpọ ba dàgbà láàrin Orílè-èdè Nàìjíríà lápapọ̀.

Comments are closed.

button