Take a fresh look at your lifestyle.

Orílè-èdè Amẹ́ríkà Pẹ̀lú China Ṣetán Ìpàdé Àpapọ̀ Ní Geneva

247

 

Ọ̀gbẹ́ni Scott Bessent àti Jamieson Greer ti orílẹ̀-èdè Amerika yóò pàdé pọ̀ pẹ̀lú He Lifeng ti ilẹ̀ China ní orílẹ̀-èdè Switzerland ní òpin ọ̀sẹ̀ yìí láti sèpàdé pọ̀ lórí ọnà àti fòpin sì ìjà òwó tó n tàbùkù bá ọrọ̀ ajé àgbáyé.

 

Ikọ̀ méjèèjì ti yóò pàdé ní Switzerland ní ìrètí wà pé wọn yóò sọ̀rọ̀ nipa ìmúlọ sílẹ̀ owó orí ọjà tó lọ sókè abbl.

 

Agbẹnusọ Mínísirì ọrọ̀ ajé ilẹ̀ China sọ nígbèyìn pé, orílẹ̀-èdè China ti gbà láti pàdé ikọ̀ ti Amẹ́ríkà fún ìpàdé náà.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button