Ẹgbẹ́ ọdọ Nàìjíríà tí dé sí Orílẹ̀-èdè Egypt fún ìdíje ọdọ ilẹ̀ Áfíríkà ní Egypt tí a ṣètò fún ọjọ́ kọkandinlọgbọn oṣù kẹ́rin sí ọjọ́ kẹ́ta oṣù karùn-ún ọdún 2025.
Ẹgbẹ́ náà tó ní àwọn olùwẹ̀ mẹ́rinlá (14), àwọn ọmọkùnrin mẹjọ (8) àti àwọn ọmọbìnrin mẹ́fà (6) ní Olùdarí àti Alàkóso Ẹgbẹ́ Àwọn olùwẹ̀ tí Nàìjíríà, Chinonye Daphey Aliyu, Akọ̀wé Gbogbogbò tí ẹgbẹ́ náà, Taiwo Oriss, Àwọn òbí tí Àwọn olùwẹ̀, Olùdarí olùkọní Yellow Yeiyah àti olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ Labake Oriretan.
Pẹ̀lú ìwọn àwọn olùwẹ̀ nínú ẹgbẹ́ yìí, Ẹgbẹ́ náà kó ní iye-meji jù pé ẹgbẹ́ yii yóò ṣé dáadáa nínú ìdíje adúláwọ̀ náà èyí tí yóò yá ọ̀pọ̀lọpọ̀ lẹ́nu.
Comments are closed.