Take a fresh look at your lifestyle.

Oníròyìn Ará Palestine Kú Nínú Ìkọ̀lù Israẹli Sí Gaza

210

 

Ìròyìn ròó pé oníròyìn ọmọ Palestine ni wọn ti sekú pa ní ọjó Ajé nígbà ti àwọn mẹ́sàn án míràn tún farapa nínú ìkọ̀lù Israẹli sì Gaza, àjọ medics and the local journalists’ union sọ yìí.

 

Ipasẹ̀ àwọn ènìyàn fihàn pé àwọn ènìyàn kan ní wọn ri pẹ̀lú èéfín nínú agọ́ gbàgede ilé ìwòsàn Nasser ni Khan Younis ni àárọ̀ kùtù ọjó Ajé.

 

Ológun Israẹli sọ nínú àkọsílẹ̀ pé àwọn ṣe ìkọ̀lù fún Hassan Aslih tó jẹ́ ẹsinòkọkú tó nń ṣe bí oníròyìn tó tún jẹ ọmọ ẹgbẹ́ ogun Hamas’ Khan Younis.

 

Aslih jẹ ìlúmọ̀ọ́ká oníròyìn Palestine ni Gaza pẹ̀lú ẹgbẹgbẹ̀rún àwọn ènìyàn tó n tẹ̀lée lórí ẹ̀rọ ayélujára ni ó farapa yánayàna bí àjọ Medics ṣe sọ.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button