Take a fresh look at your lifestyle.

Ìtọ́jú Àwọn Ògo Wẹẹrẹ: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Bauchi Buwọ́lu Ìlànà Àmúsiṣẹ́ Ti Ọdún 2025 Pẹ̀lú Àjọ UNICEF

97

 

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Bauchi ti buwọ́lu ìwé àdéhùn lórí ìlànà àmúsiṣẹ́ ti ọdún 2025 pẹ̀lú àjọ UNICEF lójúnà àti pèsè owó fún ìtọ́jú àwọn ògo wẹẹrẹ

 

Ìgbésẹ̀ náà ní àfojúsùn láti mú ìdàgbàsókè bá àwọn ará ìlú , papàá jùlọ àwọn ògo wẹẹrẹ

 

Bíbuwọ́lu ìwé àdéhun náà tí ọdún 2025 se àfirinlẹ̀ ìbásepọ̀ tí ó gún rége láàrin ìjọba ìpínlẹ̀ Bauchi àti àjọ UNICEF, èyí tí yóò mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ àti ìtọ́jú àwọn ọmọdé

Comments are closed.

button