Mínísirì Ilẹ̀ òkèèrè fun orílẹ̀-èdè China ti rọ ilé Amẹrika ní ọjó Ojoru láti má fi oju kéré ilẹ̀ China, kí wọn máa fi agbára ìjẹgàba wọn hùwa si ilẹ̀ náà nípa iwa wọn ti wọn sọ pé ilẹ̀ China ti di ẹrù jẹjẹ nípa ohun tó nise pẹlu ẹ̀rọ ayelukara, agbẹnusọ fún minisiri, Guó Jiakun sọ èyí.
Orílè-èdè China rọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti má darapọ̀ tàbí ṣe atilẹyin fún ètò ominira ilẹ̀ Taiwan, ọgbẹni Guó fi èyí kun.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san