Take a fresh look at your lifestyle.

Zimbabwe Bojú Àánú Wo Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Lásìkò Àyájọ́ Òmìnira

74

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Zimbabwe, Emmerson Mnangagwa ti fún àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ní òmìnira pẹ̀lú àwọn tí àsìkò yíyẹgi fún ti fẹ́rẹ̀ẹ̀ ẹ́ kò, lásìkò àyájọ́ òmìnira

 

Zimbabwe se ayẹyẹ òmìnira ọdún mẹ́rìnlélógójì pẹ̀lú gbígba òmìnira kúrò lọ́wọ́ àwọn amúnisìn, èyí tí ìjọba àwọn ilẹ̀ òkèèrè náà dópin ní ọdún 1980

 

Ìsẹ̀lẹ̀ òmìnira náà ni ó mú kí orúkọ Orílẹ̀-èdè náà tí ó ti ń jẹ́ Rhodesia tẹlẹri di Zimbabawe lati asiko naa

Comments are closed.