Take a fresh look at your lifestyle.

Àjèjé Ọwọ́ Kan Kò Gbẹ́rù Dórí: Títán Ìsòro Àwùjọ Nílò Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Tolórí, Tẹlẹ́mù- Mínísítà Ètò Àbò Fi Ohùn Akin Sọ̀rọ̀

61

Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ẹ̀sọ́ aláàbò gbogbo se pàtàkì láti tán ìsòro àìrajaja ààbò ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Mínísítà Fún Ètò Àbò, Muhammed Badaru ni ó sọ ọ̀rọ̀ náà láti ẹnu olùfọ̀rọ̀léde rẹ̀, Henshaw Ogubike, níbi tí ó ti sàlàyé pé àjàṣẹ́gun kò le è wáyé láìsí ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn ẹ̀ṣọ́ aláàbò gbogbo

 

Gẹ́gẹ́ bí Badaru se sọ, Orílẹ̀-èdè nílò ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn fún àseyọri tí ó peregedé nípa ètò àbò, nítorí pé àgbájọ ọwọ́ ni a fí n sọ̀yà, àjèjè ọwọ́ kan kò gbẹ́rù dórí

 

Comments are closed.