Take a fresh look at your lifestyle.

Yulia Rọ́ Àwọn Aráàlú Russia Látí Darapọ̀ Mọ́ọ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Alátakò Ní Ọjọ́ Ìdìbò

338

Yulia Navalnaya, opó àdarí àwọn alátakò Alexei Navalny, tí pé àwọn aráàlú Orílẹ̀-èdè Russia látí darapọ̀ mọ́ọ̀ fún ẹ̀honu ní ọjọ́ ìdìbò ní ọsán ọjọ́ kẹ́tadínlogún (17) Oṣù Kẹ́ta àtí látí dìbo yọ́ Ààrẹ Vladimir Putin.

Nínú fídíò ‘YouTube’ rẹ̀ kàn, Navalnaya sọ pé oún ní ireti láti ìgbà tí Ogunlọ́gọ̀ ọdọ tí jáde ní ọsẹ tó kọjá fún ìsìnkú ọkọ rẹ̀, ẹní tó kù ní ìletò ìjìyà kàn ní ọjọ́ kẹ́rìndínlogún Oṣù Kẹ́ta.

O rọ́ àwọn ènìyàn látí darapọ̀ mọ́ọ̀ ní Oṣù Kẹ́ta tí Navalny, olókìkí alátakò, tí pé fún ṣáájú kú rẹ̀.

Comments are closed.

button