Take a fresh look at your lifestyle.

313

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣé àbẹwò sí àwọn tí morí bọ́ nínú ìsẹ̀lẹ̀ iná mọ̀nàmọ́ná tó waye ní ọjọ́ Àbámẹ́ta tó kọjá ní Ìpínlẹ̀ Cross River ní Olú-ìlú náà, Calabar.


Ìjọba, nípasẹ àjọ tó n dárí iná mọ̀nàmọ́ná lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí Olùdarí àtí Oluyewo iná mọ̀nàmọ́ná tí Orílẹ̀-èdè náà, Ọ̀gbẹ́ni Aliyu Tukur àtí àwọn mìíràn ṣé ikẹdun àwọn tó kù ní General Hospital Calabar tí wọ́n sì lọ́ síbí iṣẹ̀lẹ̀ burúkú náà.

Ìròyìn àwọn tí ìṣẹ̀lẹ̀ sójú wọ́n ní ọjọ́ Sátidé Àbámẹ́ta, ọjọ Kéjì Oṣù kẹ́ta ọdún 2024 wípé, ní nnkan bí ààgó mẹ́fà irọlẹ nígbà tí Ilé-iṣẹ́ mọ̀nàmọ́ná tán iná àgbègbè náà ní gbogbo àwọn oún náà gbana, tí ó sí bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oún jẹ́. Èyí tó fá bí àwọn òpó iná wó lè àwọn ibùgbé, ọkọ̀ àtí àwọn oún ìní mìíràn.

Comments are closed.

button