Take a fresh look at your lifestyle.

Ìsẹ̀lẹ̀ Àdó Olóró Ìpínlẹ̀ Borno: Ẹgbẹ́ Akólẹ̀-Kódọ̀tí Sàfọ̀mọ́ Ara Rẹ̀

134

Ẹgbẹ́ Àkólẹ̀ Àti Àwọn Ohun Àlòpatì ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NASWDEN ti sàfọ̀mọ́  ẹgbẹ́ náà kúrò níbi ìsẹ̀lẹ̀ àdo olóró tí ó bú gbàmù ní ìlú Gubio, ìpínlẹ̀ Borno

 

Nínú àpérò kan tí ó wáyé ní ìlú Kano, ààrẹ ẹgbẹ́ náà fún Guusu Arewa, Aminu Hassan Soja sọ wipe iroyin ado oloro naa bani nínújẹ́ nígbà tí àwọn akọroyin se afiti isẹlẹ naa si ọdọ awọn ti o n sa ohun àlòpatì káàkiri ìlú

 

Ọgbeni Soja sapejuwe iroyin naa gẹgẹ bi òfegé nitori pe ijọba ipinlẹ Borno ti fi ofin de sisa awọn ohun alopati lati ọjọ ti o pe sẹyin

 

Comments are closed.

button