Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Senegal Sùn Ọjọ́ Ìdìbò Síwájú Látári Wàhálà Àwọn Olóṣèlú

274

Ààrẹ Senegal Macky Sall tí sùn ọjọ́ ìdìbò èyí tó yẹ́ kó wáyé nínú Oṣù yí síwájú látári ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹsùn idíwọ́ àwọn olùdíje láti máa kópa.

Ààrẹ náà tó tún sọ pé òun kìí yóò díje dúpo lẹyìn sáà Kéjì oún ṣùgbọ́n kó kéde ọjọ́ títún mìíràn tí ìbó náà yóò wáyé.

Láàrín àríyànjiyàn àwọn olóṣèlú náà ní pé, ìgbìmọ̀ aṣòfin kàn tí dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tó fẹ́ kópa lọ́wọ́ kọ́ látí díje dúpò.

Ọ̀gbẹ́ni Sall sọ pé “àwọn ìgbésẹ wọnyí lè dá rògbòdìyàn sílẹ̀ tó sì lè mú ìpalára bá ètò ìdìbò náà.

O fí kún pé òún yóò bẹ̀rẹ̀ “ìbáraẹnisọ̀rọ̀ gbángba tí orílẹ̀-èdè náà látí ìbó náà lọ́ ní irọ̀wọ́ àti ìrọrùn kí àlàáfíà bá lè jọba ní Orílẹ̀-èdè Senegal.”

Ṣùgbọ́n, àwọn alátakò kàn sọ́ pé ìpinnu Ààrẹ lórí sísun ọjọ́ ìbó náà síwájú ní láti dá ń kàn rú.

Comments are closed.

button