Take a fresh look at your lifestyle.

Olórí Ẹgbẹ́ Alátakò Zimbabwe Yóò Gbá Ìtusílẹ̀ Láìpẹ́

204

Olórí ẹgbẹ́ alátakò ìjọba tí Orílẹ̀-èdè Zimbabwe, Job Sikhala, yóò gbá òmìnira láìpẹ́.

Ilé-ẹjọ́ kàn ní ọjọ́ Ìṣẹgun, ọ̀gbọ̀n ọjọ́, Oṣù Kínní. Olóṣèlú náà wà ní àtimọ́le ní Oṣù Karùn-ún ọdún 2022 lẹyìn tó gbá àwọn aráàlú níyànjú látí bèrè ikú alátakò kàn Moreblessing Ali, ẹsùn èyí tó kọ̀.

Ilé-ẹjọ́ pinnu látí dá akíkanjú náà sílẹ̀ ẹní tó tí ló ẹgbẹta ọjọ́ (600days) ní àtimọ́le ṣáájú ìwádìí.

Sikhala tó jẹ́ ẹní ọdún kàn lé làádọta (51) ní Ó tí wà nínú ẹ̀wọ̀n Chikurubi ní Harare níbí tí àwọn ọdaràn tó léwu jùlọ́ ní Orílẹ̀-èdè Zimbabwe wà.

Alátakò ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí Godfrey Sithole tí wọ́n mú pẹ̀lú Sikhala náà wà níbẹ̀ pẹ̀lú.

Comments are closed.

button