Take a fresh look at your lifestyle.

Omíyalé Dá Wàhálà Sílẹ̀ Ní Kinshasa, Orílẹ̀-èdè Congo

229

Ẹ̀kún Omi ti dá wàhálà sílẹ̀ ní Kinshasa, olú ìlú DR Congo nígbà tí ẹ̀kún omi gba-ilé, gba-oko tí ó sì ba ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá jẹ́

 

Ìròyìn fi yéwa pé ọ̀ọ́dúnrún ènìyàn ni ó pàdánù ẹ̀mí látàrí omíyalé náà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá sì sòfò

 

Ní Ọjọ́bọ̀, àwọn olùgbé Kinshasa sàlàyé bí ilé ìwé, ilé ìwòsàn, ilé ìjọsìn se bá ọmi lọ.

 

Comments are closed.

button