Take a fresh look at your lifestyle.

Sẹ́nétọ̀ Mustapha Lu Àjọ Ọmọ Ogun Lọ́gọ Ẹnu Fún Ìdáàbò Bò Orílẹ̀-èdè

133

Sẹ́nétọ̀ tí ó ń sojú ààrin gbìngbìn Kwara ní Ilé ìgbìmọ̀ Asòfin, Mallam Saliu Mustapha ti gbóríyìn fún àjọ ọmọ ogun fún ìdáàbò bò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Mustapha sọ ọ̀rọ̀ náà ní ìlu Abuja nígbà tí wọ́n ń fún Ọ̀gágun Hussein Braimo tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara ní àmì ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́ ológun

 

Sẹ́nétọ̀ sàfirinlẹ̀ àwọn ìpèníjà ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí ó ń kojú àjọ ọmọ ogun, Ó wá gbóríyìn fún àjọ naa fún ìlàkààkà àti ìgbìyànjú láti dáàbò bo Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

 

 

Comments are closed.

button