Àjọ tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ọkọ̀ ojú irin ti parí ètò láti bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò alẹ́ kí ó tó di ìpín kejì nínú ọdún 2024
Alákòóso àjọ náà, Fidet Okhiria ni ó sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà níbi ìfọ̀rọ̀-wáni-lẹ́nu wò tí ó wáyé
Gẹ́gẹ́ bí ó se sọ, àjọ náà yóò bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò ọkọ̀ ojú irin ẹ̀ẹ̀mẹfà ní ojúmọ́ kan èyí tí yóò fún àwọn ènìyàn ní ànfààní ìrìnàjò ní gbogbo àsìkò