Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Kan Tí Kìí Se Ti Ìjọba Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi

336

Àjọ Aládàníi kan ti se ìdánilékọ̀ọ́ fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin ní ìpínlẹ Bauchi lórí ìmọ́tótó, ẹ̀tọ̀ ọmọbìnrin, àti ìlanilọ́yẹ̀ kúrò níbi lílo ọmọnìyàn ní ìlò ẹrú

 

Agbẹjọ́rò kan tí ó fi ìlú Bauchi se ibùjọ́kòó, Jane Onwuka ni o síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́kan tí ó wáyé, èyí tí àjọ aládàníi kan se agbáterù rẹ̀, tí ó wáye ́ní ìletò Bigi, ìjọba ìbílẹ̀ Bauchi

 

Ó tẹ̀síwájú pé ètò náà wáyé láti kọ́ àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin nípa ètò ìmọ́tótó ara wọn èyí tí yóò mú wọn jìnà sí kíkọlu àìsàn lásìkò nǹkan osù wọn.

 

Comments are closed.

button