Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹka Ètò Ìlera Ní Ìpínlẹ Kaduna Ti Pàrowà Sí Ará Ìlú Láti Gba Ìtọ́jú Ní Ààyè Tí Ó Tọ́

201

Alákòóso Ètò Ìlera ní Ẹka Ètò Ìlera Ìpínlẹ̀ Kaduna, Dókítà Sadiq Idris ti pàrọwà sí ará ìlu láti se àmójútó ìlera ara wọn, kí wọ́n sì rí i dájú pé wọ́n gba ìtọ́jú ní ààyè tí ó tọ́

 

Idris pe ìpè náà ní ọjọ́ Àìkú ní ìlú kaduna níbi ìbánisọ̀rọ̀ nípa ètò àbò tí ó wáyé ní ọjà ìlú Kawo, ijọba ìbílẹ̀ Arewa Kaduna

 

Ó sàlàyé pé gbígba ìtọ́jú ní ààyé tí ó yẹ yóò ran ará ìlú lọ́wọ́ lati ri itọju tí o peye àti àlàye lẹ́kùn-ún rẹ́rẹ́ nípa ìlànà ìlera

 

Ó sàpèjúwe ìlànà ibanisọrọ nipa eto ilera ti o waye gẹ́gẹ́ bí anfaani lati se ayẹwo ọfẹ fun ara ilu lati jeki wọn mọ ipo ti alaafia ara wọn wa.

 

Comments are closed.

button