Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Àwọn Olùdókoòwò Àti Àmójútó Ilé Iṣẹ́ Ẹka Ti Abuja Ní Adarí Tuntun

214

Wọ́n ti yan Emeka Obegolu gẹ́gẹ́ bí adaŕi ẹgbẹ́ olùdókoòwò àti àmójútó Ilé Iṣẹ́, ẹka tí Abuja

 

Ọgbẹ́ni Obegolu, ẹni tí wọ́n yànsípò níbi ìpàdé ọlọ́dọọdún olọ́dún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n irú rẹ̀ ní ìlú Abuja sọ wípé ìtẹ̀síwájú àjọ náà ni ó jẹ òun lógún, ó wá rọ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà láti fọwọ́sowọ́pọ̀ kí ìdàgbàsókè náà le è wáyé

 

Ó wá sàlàyé àwọn àfojúsùn rẹ̀ èyí tí yóò mú ìlọsíwájú bá ẹgbẹ́ náà, lára wọn ní ìpèsè oun amáyédẹrùn, síṣe àtúnṣe ohun èlò ẹgbẹ́, àfojúsùn rere, ìlànà ètò ọrọ̀ ajé tí ó peregedé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

 

Comments are closed.

button