Ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun pèsè ohun èlò fún àwọn aláboyún ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dógún èyí tí yóò mú kí wọn bí wẹ́rẹ́, ninú ètò kan tí wọ́n pe àkọmọ̀nà rẹ ní Abíwẹ́rẹ́
Kọmísọ́nà fún ètò ìlera, Dókítà Tomi Coker ni ó sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó n bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ lórí ètò náà ní ọjọ́ Ẹtì, ní ìlú Abẹokuta
Coker sàlàyé pé ètò náà wáyé láti fún àwọn aláboyún ní itọju ti o peye ki wọn le è bí wẹ́rẹ́.
Leave a Reply