Alákòóso iṣẹ́ Ààrẹ, Fẹmi Gbajabiamila ti salaye pe ijọba apapọ ń là kààkà láti ri daju pe ètò ẹ̀yáwó fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbérasọ ni osu kíní, ọdún 2024
O tẹsiwaju pe eto naa yoo fun awọn akẹkọọ ni anfaani ẹyawo fun ìtẹ̀síwájú ẹkọ wọn
Gbajabiamila sọ ọrọ naa ni ilu Eko nibi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ eyi ti àkọmọ̀nà rẹ̀ jẹ́ “ síṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ìdàgbàsókè Ọrọ̀ Aje” eyi ti o waye nibi ayẹyẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde ni ile iwe giga YABATECH, ni ilu Eko.
Leave a Reply