Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Se Àwọn Alákatakítí Báṣu-bàṣu- Adarí Àjọ Ọmọ Ogun Pàṣẹ

0 363

Àṣẹ ti wá fún àwọn Ọmọ Ológun láti palẹ̀ àwọn alákatakítí mọ́, kí wọn sì ri dájú pé gbogbo orípa wọ́n parẹ́ pátápátá

 

Adarí Àjọ ọmọ ogún ti ikọ̀ HADIN KAI tí Ẹkùn Ìlà Oòrùn Arewa, Ọ̀gágun Gold Chibuisi ni ó pàṣẹ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó ń bá ikọ̀ ọmọ ogun sọ̀rọ̀ ní Madagali, Ìpínlẹ̀ Adamawa

 

Ọ̀gágun Chibuisi se àbẹ̀wò sí àwọn ọmọ ológun, Ó gbàwọ́n níyànjú láti tẹ̀síwájú àseyọrí wọn, Ó sì gbóríyìn fún iṣẹ́ takun-takun tí wọn ń se.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button