Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Darapọ̀ Mọ́ Iṣẹ́ Ológun- Olurẹmi Tinubu Pàrọwà Sí Àwọn Obìnrin

0 189

Aya Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Olurẹmi Tinubu ti késí olórí àwọn ọmọ ogun láti gba àwọn obìnrin níyànjú kí wọ́n le è darapọ̀ mọ́ àjọ náà

 

Ó pe ìpè náà ní ọ́ọ́fìsì àpapọ̀ àjọ ọmọ ogun níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ kan èyítí ó pèpè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ takọ-tabo láti tán ìsòro àìrajaja ètò àbò.

 

Oluremi, ẹni tí aya igbákejì ààrẹ, Nana Shettima sojú fún gbóríyìn fún àjọ ọmọ ogun  fún ìkẹ́sẹjárí ètò náà

 

Aya ààrẹ sàfirinlẹ̀ pé, ètò àbò se kókó ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, nítorí náà ó se pàtàkì fún olúkúlùkù láti f’ọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ omọ ogun.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button